November 23, 2017
November 23, 2017
Always have a good memory of you Sister Tosin....continue to rest in the bosom of our Lord !
Oluwatosin Alake
Omo Olofa mojo
Omo Olalomi
Omo Abisu joko
Omo ija kandi loro ofa
Omo ija kan, ija kan ti won ja lofa nile Olalomi
Molo soju ebe
Molo soju poro ninu oko
Omo la ree kole dogba
Omo ikan o gbodo ju kan
Omo bikan ba jukan nile Olalomi
Oba ni pin won ro ro
Oba o pin won ro ro mo
Ti e diran.
my beloved sister went to be wt d Lord.
Oluwatosin, though u re gone, ur memories still lingers on.....