ForeverMissed
His Life

ORIKI IDILE DADDY MI -OLASUPO GANIYU MOFIOLORUNSO ASHIMI-ADEOKUN.

ORIKI IDILE BABA DADDY- G.O

OMO ADEOKUN ABALANKO,OMO ODE    IDI  IGBALA,

OMO ORISA FI DI AMU KALE INU NBI AJERE,

OMO MUPA ASAYAN,

OMO ALEGUN ,MAA DE YIN

OMO ADALEKO, OMO OLISA NI  IJEBU ODE.

SUN RE E OO, KI OLUWA BAWA  KEYIN NI ORUN RE E OO.

 

ORIKI DADDY MI NI IDILE IYA

 OMO ARIJE NI MOPE ,

OMO  EGBO   MOGUNN  , ARAA   IJAMO

 OMO WON NI ,IDEPO NI  IJEBU  ODE.

ORUN REE OO  DADDY  G.O  ,KI OLUWA KI O SE ALABO LORI  AYA , GBOGBO OMO ATI AWON  OMO MO , TI  EFISILE LO. GBOGBO EBI  LAPAPO KI OLUWA KI OSO WAOO. AMIN OO.