Olufemi, Daddy Olu iku O je ka jo gbadun ara wa dale, mo n se Idaro leyin re oko dada, abiyamo gidi, olore mi.
Mo wo iwaju mi,mi o ri oko mi mo, mo wo eyin wo, mi o ri baba omo dada. Ko si eni ti o le bami wa alajani mi lo...baba awon omo dada. Baba awon ewe were leleta, baba awon Olorire omo, baba akorin temple, olufe adugbo, olufe ijo olorun gbogbo, olutoju alaini, oko mi ti won mo nile loko.
Awon ebi re nse leede leyin re o. Gbogbo ibi ti o ti mu aya won ni Aku idele re o, ile iya re, ile baba re nki o. Oludeji omo Opawale ti o se gbagbe ni gbogbo ojo ko se gbagbe ninu ebi ati ninu ijo olorun gbogbo, lomode lagba nse ilede leyin re.
Ijo CAC Eleta, baba ewe, awon omo naa o le gbagbe asiko re.
Oko mi owon, oko ti o se paro,emi o le gbagbe re titi, awon omo re o le gbagbe re lailai beni awon ebi mi ko le gbagbe re o. Oko mi, adunbarin ma mosi, adunbarin ma jiya, Ajani mi to ri ore ofe gba dojo ale, sun re o. Ni ojo ti a o ba pade ni paradise, ayo ni o jo fun wa. Oludeji omo Aderonke, omo Opawale gbogbo aye nse ilede leyin re o sun re o, ile ti o fi sile ko ni baje o.
Aya re tooto
Olubola Opawale