Your browser has cookies disabled. Make sure your cookies are enabled and try again. If you believe that there is an error, please contact us for assistance.
Ikú kòjé kí a gbádùn re bí ó titó àti bí ó tiye. Kòjé kí o je óunje omo pé pèlú. Àmó taaní wá tí yoo ma bá Olórun ro ejó? Nítorí wípé, òkú ń sunkún òkú ni, akásolérí ń sunkún ara won
ni. Sùn re, omo, Àjàlà òkín. Ódòwúrò.
Passed away on April 24, 2019 in Ìbàdàn., Òyó State., Nigeria
This memorial website was created in memory of our loved one, Omo Oba Omóbólánlé Oláyemí (Nee Oyinlolá) . We will remember her forever.