ForeverMissed
Large image
Her Life

About Madam Victoria Oluyemi Adewale

July 7, 2021
Madam Victoria Oluyemi Abeke Adewale was born on 4th August, 1937 to Late Pa. James Karounwi Ajani and Late Madam Alice Morenike Ajani (Nee Bankole) in Eredo (Egbado  - presently Yewa side of Ogun State). Her father, from Agbole Olosi, Totoro, Abeokuta, Ogun State was a very successful farmer and trader and hence his sojourn to Eredo where had most of his children.

Mama moved to join her elder sister in Arigbajo, Ogun State at about the age of 10 to learn the art of trading of Ofada Rice all around Ifo. She later moved to Ebutte-Metta in Lagos at about age 14, after the death of her sister in Arigbajo to join her older cousin to expand her rice trading experience until her marriage to Late Pa. Peters Oludele Adewale at about age 20 and her marriage was blessed with many children, grandchildren and great grandchildren.

Mama had passion and wide experience in trading. She dealt in various forms of commodities such as rice, bread, provisions etc.

While mama had no formal education, she had a deep passion for education and had raised a lot of professionals such as accountants, engineers, administrators, medical practioners, successful business peoples and so on, who were and are highly placed locally and internationally.

Mama was a devoted Christian, a member of Deeper Life Bible Church. She was a lover of children. She was loved by many because of her intelligence, listening ears, good guidance as well as motherly advices.

May her soul rest in peace

Oriki Mama

July 7, 2021
Victoria Oluyemi Abeke Adewale

Omo James Karounwi Ajani

Ajani omo Karounwi

Omo osun lakesan, Iseri omo oloko

Omo olu nla, Omo agbo’dere

Omo k’afopa wa k’afaje wa

Kawa f’ogede gede owo wa d’ele iseri

Omo erin wo opa

Omo agberindinlogun aje

Akingbowo oko lowo osun

Eniba gbowo oko l’owo osun onitowun akopa,

K’aje agbona ajirun lo

Omo oniyan koko to megbe j’akosu lo

Omo aji sunwo lemoso

Omo aji fojo gbogbo dara bi egbin

B’ewure ba burewa lemoso won a mamuu paje

Aguntan bolojo bo ba burewa lemoso won a mamuu paje

Ototo eeyan lo burewa legiri

Gbogbo won dilekun won nsukun gburu gbu

Akii burewa legiri, gbogbowa lase ndara bi owo miiri

Ara ejigbo

Ejigbo ko l’ode

Omo afide seewo

Opa oje lakijaa te

Eyin o je pakija lajo

Omo aperan nla b’aje

Ewu owu

Omo asogba karisa

Ewu kii memu

Ogiriyan o maa j’ogongo ope

Kini ipako ope npe marin lode se?

…and so on

Oriki Pa Adewale

August 2, 2021
Oriki Pa Peters Oludele Adewale


Kabiyesi...Iba o

Omo s’ela, Omo ‘luade

Omo gbadela, Omo kijala ti laarugba

Feyilaal’oju tilufoosin

Lufoos’ogboede, Omo kijalamoko

Kijalamoko melee

Ara ‘kerejatorolu s’ale, Omotana otoj’esu

Enide’kaereja abolosa oko, Abalarere pelue

Omo oriawure, Omo patan f’owol’de

Omo agboriaga s’ogun

Omo olubebe bi, Omo to’lawo

T’olawo omo aayol’oyo

Abikanlu, omo otutu t’ont’owulara

Omo gbadeg’esin, eleyin’ju ire’binrin

Omo oba eleyin ike… ab’erin seeeeeen…

Kirakita mama f’esinte miii…

Omo oba bi ori mayenl’oye

,,,and so on...